Gẹnẹsisi 15:20
Genesis 15:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
àti ti ará Hiti, àti ti ará Peresi, àti ti ará Refaimu.
Genesis 15:20 in English
Genesis 15:20 · Berean Standard Bible
Hittites, Perizzites, Rephaites,
Context
18Ní ọjọ́ náà gan an ni Olúwa dá májẹ̀mú pẹ̀lú Abramu, ó sì wí pé, “Àwọn ìran rẹ ni èmi yóò fi ilẹ̀ yìí fún, láti odò Ejibiti dé odò ńlá Eufurate: 19ilẹ̀ àwọn ará Keni, àti ti ará Kenissiti, àti ará Kadmoni, 20àti ti ará Hiti, àti ti ará Peresi, àti ti ará Refaimu. 21Àti ti ará Amori, àti ti ará Kenaani, àti ti ará Girgaṣi àti ti ará Jebusi.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.