Native Bible

Ezra 7:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ọmọ Serahiah, ọmọ Ussi, ọmọ Bukki,

Ezra 7:4 in English

Ezra 7:4 · Berean Standard Bible

the son of Zerahiah, the son of Uzzi, the son of Bukki,

Context

2ọmọ Ṣallumu, ọmọ Sadoku, ọmọ Ahitubu, 3ọmọ Amariah, ọmọ Asariah, ọmọ Meraioti, 4ọmọ Serahiah, ọmọ Ussi, ọmọ Bukki, 5ọmọ Abiṣua, ọmọ Finehasi, ọmọ Eleasari, ọmọ Aaroni olórí àlùfáà— 6Esra yìí sì gòkè wá láti Babeli. Olùkọ́ tí ó ní ìmọ̀ ìjìnlẹ̀ nípa òfin Mose, èyí tí Olúwa, Ọlọ́run Israẹli, ti fi fún wọn. Ọba sì fi gbogbo ohun tí ó béèrè fún un, nítorí ọwọ́ Olúwa Ọlọ́run wà lára rẹ̀.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.