Native Bible

Ezra 2:4 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ṣefatia jẹ́ òjìdínnírinwó ó lé méjìlá (372)

Ezra 2:4 in English

Ezra 2:4 · Berean Standard Bible

the descendants of Shephatiah, 372;

Context

2Àwọn wọ̀nyí bá Serubbabeli, Jeṣua, Nehemiah, Seraiah, Reelaiah, Mordekai, Bilṣani, Mispari, Bigfai, Rehumu àti Baanah wá). Iye àwọn ọkùnrin àwọn ènìyàn Israẹli. 3Àwọn ọmọ Paroṣi jẹ́ ẹgbàá ó lé méjìléláàádọ́sàn-án (2,172) 4Ṣefatia jẹ́ òjìdínnírinwó ó lé méjìlá (372) 5Arah jẹ́ ẹgbẹ̀rin ó dín mẹ́ẹ̀ẹ́dọ́gbọ̀n (775) 6Pahati-Moabu (láti ipasẹ̀ àwọn ọmọ Jeṣua àti Joabu) jẹ́ ẹgbẹ̀rún méjì àti ẹgbẹ̀rin lé méjìlá (2,812)

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.