Esekiẹli 27:36
Ezekiel 27:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn oníṣòwò láàrín àwọn orílẹ̀-èdè dún bí ejò sí ọ ìwọ yóò sì jẹ́ ẹ̀rù ìwọ kì yóò sì ṣí mọ́ láéláé.’ ”
Ezekiel 27:36 in English
Ezekiel 27:36 · Berean Standard Bible
Those who trade among the nations hiss at you; you have come to a horrible end and will be no more.’”
Context
34Ní ìsinsin yìí tí Òkun fọ ọ túútúú
nínú ibú omi;
nítorí náà òwò rẹ àti gbogbo ẹgbẹ́ rẹ
ní àárín rẹ,
ni yóò ṣubú. 35Ẹnu yóò ya gbogbo àwọn ti ń gbé
ní erékùṣù náà sí ọ
jìnnìjìnnì yóò bo àwọn ọba wọn,
ìyọnu yóò sì han ní ojú wọn. 36Àwọn oníṣòwò láàrín àwọn orílẹ̀-èdè dún bí ejò sí ọ
ìwọ yóò sì jẹ́ ẹ̀rù
ìwọ kì yóò sì ṣí mọ́ láéláé.’ ”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.