Native Bible

Ezekiel 18:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọ̀rọ̀ Olúwa tún tọ̀ mí wá wí pé:

Ezekiel 18:1 in English

Ezekiel 18:1 · Berean Standard Bible

Then the word of the LORD came to me, saying,

Context

1Ọ̀rọ̀ Olúwa tún tọ̀ mí wá wí pé: 2“Kín ni ẹ̀yin rò tí ẹ̀yin fi ń pa òwe nípa Israẹli wí pé: “ ‘Àwọn baba ti jẹ èso àjàrà kíkan, eyín àwọn ọmọ sì kan.’ 3“Bí mo ti wà láààyè ni Olúwa Olódùmarè wí, ẹ̀yin kí yóò pa òwe yìí mọ́ ni Israẹli.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.