Eksodu 39:35
Exodus 39:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
àpótí ẹ̀rí pẹ̀lú àwọn òpó rẹ̀ àti ìbòrí àánú;
Exodus 39:35 in English
Exodus 39:35 · Berean Standard Bible
the ark of the Testimony * with its poles and the mercy seat;
Context
33Wọ́n sì mú tabanaku náà tọ Mose wá:
àgọ́ náà àti gbogbo ohun ọ̀ṣọ́ rẹ̀, ìkọ́ rẹ̀, pákó rẹ̀, ọ̀pá rẹ̀, òpó rẹ̀ àti àwọn ihò ìtẹ̀bọ̀ rẹ̀; 34ìbòrí awọ àgbò tí a kùn ní pupa, ìbòrí awọ àti ìji aṣọ títa; 35àpótí ẹ̀rí pẹ̀lú àwọn òpó rẹ̀ àti ìbòrí àánú; 36tábìlì pẹ̀lú gbogbo ohun èlò rẹ̀ àti àkàrà ìfihàn; 37ọ̀pá fìtílà kìkì wúrà pẹ̀lú ipele fìtílà rẹ̀ àti gbogbo ohun èlò rẹ̀, àti òróró fún títanná rẹ̀;
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.