Native Bible

Exodus 28:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ní ẹsẹ̀ kẹta, jasiniti, agate, àti ametisiti;

Exodus 28:19 in English

Exodus 28:19 · Berean Standard Bible

in the third row a jacinth, an agate, and an amethyst;

Context

17Nígbà náà ni ìwọ yóò de òkúta oníyebíye mẹ́rin sára ẹsẹ̀ rẹ̀. Ní ẹsẹ̀ àkọ́kọ́ ni kí rúbì, topasi àti berili wà; 18ní ẹsẹ̀ kejì turikuose, emeradi, safire, àti diamọndi; 19ní ẹsẹ̀ kẹta, jasiniti, agate, àti ametisiti; 20ní ẹsẹ̀ kẹrin, topasi, àti óníkìsì àti jasperi. A ó sì tò wọ́n sí ojú wúrà ní dìde wọn. 21Òkúta méjìlá yóò wà, ọ̀kọ̀ọ̀kan fún orúkọ àwọn ọmọ Israẹli olúkúlùkù èdìdì àmì pẹ̀lú orúkọ ẹnìkọ̀ọ̀kan bí ẹ̀yà Israẹli méjìlá.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.