Native Bible

Exodus 26:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

kí o sì ṣe pákó méjì fún igun ní ìhà ẹ̀yìn.

Exodus 26:23 in English

Exodus 26:23 · Berean Standard Bible

and two frames for the two back corners of the tabernacle,

Context

21àti ogójì ihò ìtẹ̀bọ̀ fàdákà méjì ní abẹ́ pákó kọ̀ọ̀kan. 22Kí ìwọ kí ó ṣe pákó mẹ́fà sì ìkangun, ní ìkangun ìhà ìwọ̀-oòrùn àgọ́ náà, 23kí o sì ṣe pákó méjì fún igun ní ìhà ẹ̀yìn. 24Ní igun méjèèjì yìí, wọ́n gbọdọ̀ jẹ́ méjì láti ìdí dé orí rẹ̀, a ó sì so wọ́n pọ̀ sí òrùka kan: méjèèjì yóò sì rí bákan náà. 25Wọn ó sì jẹ́ pákó mẹ́jọ, àti ihò ìtẹ̀bọ̀ fàdákà mẹ́rìnlélógún, méjì wà ní ìsàlẹ̀ ọ̀kọ̀ọ̀kan.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.