Eksodu 17:15
Exodus 17:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Mose sì tẹ́ pẹpẹ kan, ó sì sọ orúkọ pẹpẹ náà ní Olúwa ni Àsíá mi.
Exodus 17:15 in English
Exodus 17:15 · Berean Standard Bible
And Moses built an altar and named it The LORD Is My Banner.*
Context
13Joṣua sì fi ojú idà ṣẹ́gun àwọn ará Amaleki. 14Olúwa sì sọ fun Mose pé. “Kọ èyí sì inú ìwé fún ìrántí, kí o sì sọ fún Joṣua pẹ̀lú; nítorí èmi yóò pa ìrántí Amaleki run pátápátá kúrò lábẹ́ ọ̀run.” 15Mose sì tẹ́ pẹpẹ kan, ó sì sọ orúkọ pẹpẹ náà ní Olúwa ni Àsíá mi. 16Ó wí pé, “A gbé ọwọ́ sókè sí ìtẹ́ Olúwa. Olúwa yóò bá Amaleki jagun láti ìran dé ìran.”
17.7 Massatúmọ̀ sí ìdánwò
17.7 Meribatúmọ̀ sí kíkùn
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.