Native Bible

Exodus 12:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni ni ilẹ̀ Ejibiti pé,

Exodus 12:1 in English

Exodus 12:1 · Berean Standard Bible

Now the LORD said to Moses and Aaron in the land of Egypt,

Context

1Olúwa sọ fún Mose àti Aaroni ni ilẹ̀ Ejibiti pé, 2“Oṣù yìí ni yóò jẹ́ oṣù àkọ́kọ́ fún yín, oṣù àkọ́kọ́ nínú ọdún yín. 3Sọ fún gbogbo àwọn ènìyàn Israẹli pé ni ọjọ́ kẹwàá oṣù yìí, ọkùnrin kọ̀ọ̀kan yóò mú ọ̀dọ́-àgùntàn kọ̀ọ̀kan fún ìdílé rẹ̀, ọ̀kan fún agbo ilé kọ̀ọ̀kan.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.