Native Bible

Ecclesiastes 3:7 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

ìgbà láti ya àti ìgbà láti rán ìgbà láti dákẹ́ àti ìgbà láti sọ̀rọ̀,

Ecclesiastes 3:7 in English

Ecclesiastes 3:7 · Berean Standard Bible

a time to tear and a time to mend, a time to be silent and a time to speak,

Context

5ìgbà láti tú òkúta ká àti ìgbà láti ṣà wọ́n jọ ìgbà láti súnmọ́ àti ìgbà láti fàsẹ́yìn, 6ìgbà láti wá kiri àti ìgbà láti ṣàì wá kiri ìgbà láti pamọ́ àti ìgbà láti jù nù, 7ìgbà láti ya àti ìgbà láti rán ìgbà láti dákẹ́ àti ìgbà láti sọ̀rọ̀, 8ìgbà láti ní ìfẹ́ àti ìgbà láti kórìíra ìgbà fún ogun àti ìgbà fún àlàáfíà. 9Kí ni òṣìṣẹ́ jẹ ní èrè nínú wàhálà rẹ̀?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.