Deuteronomi 33:5
Deuteronomy 33:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Òun ni ọba lórí Jeṣuruni ní ìgbà tí olórí àwọn ènìyàn péjọpọ̀, pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà Israẹli.
Deuteronomy 33:5 in English
Deuteronomy 33:5 · Berean Standard Bible
So the LORD became King in Jeshurun * when the leaders of the people gathered, when the tribes of Israel came together.
Context
3Nítòótọ́, ó fẹ́ràn àwọn ènìyàn an rẹ̀,
gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́ wà ní ọwọ́ rẹ̀.
Ní ẹsẹ̀ rẹ̀ ni wọ́n ti foríbalẹ̀,
àti lọ́dọ̀ rẹ̀ ni wọ́n ti ń gba ọ̀rọ̀, 4òfin tí Mose fi fún wa,
ìní ti ìjọ ènìyàn Jakọbu. 5Òun ni ọba lórí Jeṣuruni
ní ìgbà tí olórí àwọn ènìyàn péjọpọ̀,
pẹ̀lú àwọn ẹ̀yà Israẹli. 6“Jẹ́ kí Reubeni yè kí ó má ṣe kú,
tàbí kí ènìyàn rẹ mọ níwọ̀n.” 7Èyí ni ohun tí ó sọ nípa Juda:
“Olúwa gbọ́ ohùn Juda
kí o sì mú tọ àwọn ènìyàn rẹ̀ wá.
Kí ọwọ́ rẹ̀ kí ó tó fún un,
kí ó sì ṣe ìrànlọ́wọ́ fún lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá rẹ̀!”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.