Deuteronomi 33:1
Deuteronomy 33:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Èyí ni ìbùkún tí Mose ènìyàn Ọlọ́run bùkún fún àwọn ọmọ Israẹli kí ó tó kú.
Deuteronomy 33:1 in English
Deuteronomy 33:1 · Berean Standard Bible
This is the blessing that Moses the man of God pronounced upon the Israelites before his death.
Context
1Èyí ni ìbùkún tí Mose ènìyàn Ọlọ́run bùkún fún àwọn ọmọ Israẹli kí ó tó kú. 2Ó sì wí pé,
“Olúwa ti Sinai wá,
ó sì yọ sí wọn láti Seiri wá
ó sì tàn án jáde láti òkè Parani wá.
Ó ti ọ̀dọ̀ ẹgbẹgbàarùn-ún àwọn mímọ́ wá
láti ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ ni òfin kan a mú bí iná ti jáde fún wọn wá. 3Nítòótọ́, ó fẹ́ràn àwọn ènìyàn an rẹ̀,
gbogbo àwọn ènìyàn mímọ́ wà ní ọwọ́ rẹ̀.
Ní ẹsẹ̀ rẹ̀ ni wọ́n ti foríbalẹ̀,
àti lọ́dọ̀ rẹ̀ ni wọ́n ti ń gba ọ̀rọ̀,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.