2 Timotiu 4:21
2 Timothy 4:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Sa ipá rẹ láti tètè wá ṣáájú ìgbà òtútù. Eubulu kí ọ, àti Pudeni, àti Linu, Klaudia, àti gbogbo àwọn arákùnrin.
2 Timothy 4:21 in English
2 Timothy 4:21 · Berean Standard Bible
Make every effort to come to me before winter. Eubulus sends you greetings, as do Pudens, Linus, Claudia, and all the brothers.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.