Native Bible

2 Samuel 23:24 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ọ̀kan nínú àwọn ọgbọ̀n náà: Asaheli arákùnrin Joabu sì Jásí Elhanani ọmọ Dodo ti Bẹtilẹhẹmu;

2 Samuel 23:24 in English

2 Samuel 23:24 · Berean Standard Bible

Now these were members of the Thirty:* Asahel the brother of Joab, Elhanan son of Dodo of Bethlehem,

Context

22Nǹkan wọ̀nyí ní Benaiah ọmọ Jehoiada ṣe, ó sì ní orúkọ nínú àwọn ọkùnrin alágbára mẹ́ta náà. 23Nínú àwọn ọgbọ̀n náà, òun ní ọlá jùlọ, ṣùgbọ́n òun kò tó àwọn mẹ́ta ti ìṣáájú. Dafidi sì fi í ṣe ìgbìmọ̀ rẹ̀. 24Ọ̀kan nínú àwọn ọgbọ̀n náà: Asaheli arákùnrin Joabu sì Jásí Elhanani ọmọ Dodo ti Bẹtilẹhẹmu; 25Ṣamma ará Haroditi, Elika ará Harodi. 26Helesi ará Palti, Ira ọmọ Ikẹsi ará Tekoa;

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.