2 Samuẹli 22:51
2 Samuel 22:51 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Òun ni ilé ìṣọ́ ìgbàlà fún ọba rẹ̀; ó sì fi àánú hàn fún ẹni àmì òróró rẹ̀, fún Dafidi, àti fún irú-ọmọ rẹ̀ títí láéláé.”
2 Samuel 22:51 in English
2 Samuel 22:51 · Berean Standard Bible
Great salvation He brings to His king. He shows loving devotion to His anointed, to David and his descendants forever.”
Context
49Àti ẹni tí ó gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọ̀tá mi.
Ìwọ sì gbé mi sókè ju àwọn tí ó kórìíra mi lọ;
ìwọ sì gbà mí kúrò lọ́wọ́ àwọn ọkùnrin oníwà ipá. 50Nítorí náà èmi ó fi ọpẹ́ fún ọ, Olúwa,
láàrín àwọn àjèjì orílẹ̀-èdè, èmi ó sì kọrin sí orúkọ rẹ. 51“Òun ni ilé ìṣọ́ ìgbàlà fún ọba rẹ̀;
ó sì fi àánú hàn fún ẹni àmì òróró rẹ̀,
fún Dafidi, àti fún irú-ọmọ rẹ̀ títí láéláé.”
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.