2 Samuẹli 22:23
2 Samuel 22:23 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nítorí pé gbogbo ìdájọ́ rẹ̀ ni ó wà níwájú mi; àti ní ti òfin rẹ̀, èmi kò sì yapa kúrò nínú wọn.
2 Samuel 22:23 in English
2 Samuel 22:23 · Berean Standard Bible
For all His ordinances are before me; I have not disregarded His statutes.
Context
21“Olúwa sán án fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi;
ó sì san án fún mi gẹ́gẹ́ bí mímọ́ ọwọ́ mi. 22Nítorí pé èmi pa ọ̀nà Olúwa mọ́,
èmi kò sì fi ìwà búburú yapa kúrò lọ́dọ̀ Ọlọ́run mi. 23Nítorí pé gbogbo ìdájọ́ rẹ̀ ni ó wà níwájú mi;
àti ní ti òfin rẹ̀, èmi kò sì yapa kúrò nínú wọn. 24Èmi sì wà nínú ìwà títọ́ sí í,
èmi sì pa ara mi mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ mi. 25Olúwa sì san fún mi gẹ́gẹ́ bí òdodo mi,
gẹ́gẹ́ bí ìwà mímọ́ mi níwájú rẹ̀.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.