Native Bible

2 Ọba 24:21

Yoruba· Change

2 Kings 24:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

(20) Nísinsin yìí Sedekiah sì ṣọ̀tẹ̀ sí ọba Babeli.

Context

19Ó sì ṣe búburú ní ojú Olúwa, gẹ́gẹ́ bí Jehoiakimu ti ṣe. 20Nítorí tí ìbínú Olúwa, ni gbogbo èyí ṣe ṣẹ sí Jerusalẹmu, àti Juda, ní òpin ó ta wọ́n nù kúrò níwájú rẹ̀. 21(20) Nísinsin yìí Sedekiah sì ṣọ̀tẹ̀ sí ọba Babeli.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.