Native Bible

2 Corinthians 13:14 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa, àti ìfẹ́ Ọlọ́run, àti ìdàpọ̀ ti Èmí Mímọ́, kí ó wà pẹ̀lú gbogbo yín.

2 Corinthians 13:14 in English

2 Corinthians 13:14 · Berean Standard Bible

The grace of the Lord Jesus Christ, and the love of God, and the fellowship of the Holy Spirit be with all of you.*

Context

12Ẹ fi ìfẹnukonu mímọ́ kí ara yín. 13Gbogbo àwọn ènìyàn Ọlọ́run níbi kí i yín. 14Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa, àti ìfẹ́ Ọlọ́run, àti ìdàpọ̀ ti Èmí Mímọ́, kí ó wà pẹ̀lú gbogbo yín.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.