2 Kọrinti 13:13
2 Corinthians 13:13 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Gbogbo àwọn ènìyàn Ọlọ́run níbi kí i yín.
2 Corinthians 13:13 in English
2 Corinthians 13:13 · Berean Standard Bible
All the saints send you greetings.
Context
11Ní àkótán, ará ó dì gbòóṣe, ẹ ṣe àtúnṣe ọ̀nà yín, ẹ tújúká, ẹ jẹ́ onínú kan, ẹ máa wà ní àlàáfíà, Ọlọ́run ìfẹ́ àti ti àlàáfíà yóò wà pẹ̀lú yín. 12Ẹ fi ìfẹnukonu mímọ́ kí ara yín. 13Gbogbo àwọn ènìyàn Ọlọ́run níbi kí i yín. 14Oore-ọ̀fẹ́ Jesu Kristi Olúwa, àti ìfẹ́ Ọlọ́run, àti ìdàpọ̀ ti Èmí Mímọ́, kí ó wà pẹ̀lú gbogbo yín.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.