2 Kronika 33:25
2 Chronicles 33:25 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbà náà, gbogbo àwọn ènìyàn ilẹ̀ náà pa gbogbo àwọn tí wọ́n ṣọ̀tẹ̀ sí ọba Amoni, wọ́n sì mú Josiah ọmọ rẹ̀ jẹ ọba ní ipò rẹ̀.
2 Chronicles 33:25 in English
2 Chronicles 33:25 · Berean Standard Bible
But the people of the land killed all those who had conspired against King Amon, and they made his son Josiah king in his place.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.