2 Kronika 29:12
2 Chronicles 29:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbà náà àwọn ọmọ Lefi wọ̀nyí múra láti ṣe iṣẹ́: nínú àwọn ọmọ Kohati, Mahati ọmọ Amasai: àti Joẹli ọmọ Asariah; nínú àwọn ọmọ Merari, Kiṣi ọmọ Abdi àti Asariah ọmọ Jehaleeli; nínú àwọn ọmọ Gerṣoni, Joah, ọmọ Simma àti Edeni ọmọ Joah;
2 Chronicles 29:12 in English
2 Chronicles 29:12 · Berean Standard Bible
Then the Levites set to work: Mahath son of Amasai and Joel son of Azariah from the Kohathites; Kish son of Abdi and Azariah son of Jehallelel from the Merarites; Joah son of Zimmah and Eden son of Joah from the Gershonites;
Context
10Nísinsin yìí ó wà ní ọkàn mi láti bá Olúwa Ọlọ́run Israẹli dá májẹ̀mú. Bẹ́ẹ̀ ni kí ìbínú rẹ̀ kíkan kí ó lè yípadà kúrò lọ́dọ̀ wa. 11Àwọn ọmọ mi, ẹ má ṣe jáfara nísinsin yìí, nítorí tí Olúwa ti yàn yín láti dúró níwájú rẹ̀ láti sin, kí ẹ sì máa ṣe ìránṣẹ́ níwájú rẹ̀ àti láti sun tùràrí.” 12Nígbà náà àwọn ọmọ Lefi wọ̀nyí múra láti ṣe iṣẹ́:
nínú àwọn ọmọ Kohati,
Mahati ọmọ Amasai: àti Joẹli ọmọ Asariah;
nínú àwọn ọmọ Merari,
Kiṣi ọmọ Abdi àti Asariah ọmọ Jehaleeli;
nínú àwọn ọmọ Gerṣoni,
Joah, ọmọ Simma àti Edeni ọmọ Joah; 13nínú àwọn ọmọ Elisafani,
Ṣimri àti Jeieli;
nínú àwọn ọmọ Asafu,
Sekariah àti Mattaniah; 14nínú àwọn ọmọ Hemani,
Jehieli àti Ṣimei;
nínú àwọn ọmọ Jedutuni,
Ṣemaiah àti Usieli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.