Native Bible

2 Chronicles 24:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Joaṣi ṣe ohun tí ó dára ní ojú Olúwa ní gbogbo àkókò Jehoiada àlùfáà.

2 Chronicles 24:2 in English

2 Chronicles 24:2 · Berean Standard Bible

And Joash did what was right in the eyes of the LORD all the days of Jehoiada the priest.

Context

1Joaṣi jẹ́ ọmọ ọdún méje nígbà tí ó jẹ ọba, ó sì jẹ ọba ní Jerusalẹmu fún ogójì ọdún. Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Sibia ti Beerṣeba. 2Joaṣi ṣe ohun tí ó dára ní ojú Olúwa ní gbogbo àkókò Jehoiada àlùfáà. 3Jehoiada yan ìyàwó méjì fún un, ó sì ní àwọn ọmọkùnrin àti àwọn ọmọbìnrin. 4Ní àkókò kan, Joaṣi pinnu láti tún ilé Olúwa ṣe.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.