1 Timotiu 2:15
1 Timothy 2:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ṣùgbọ́n a ó gbà àwọn obìnrin là nípa ìbímọ wọn, bí wọ́n bá dúró nínú ìgbàgbọ́, ìfẹ́, àti ìwà mímọ́ pẹ̀lú ìwà àìrékọjá.
1 Timothy 2:15 in English
1 Timothy 2:15 · Berean Standard Bible
Women, however, will be saved through childbearing, if they continue in faith, love, and holiness, with self-control.
Context
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.