Native Bible

1 Kings 17:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa tọ Elijah wá pé,

1 Kings 17:2 in English

1 Kings 17:2 · Berean Standard Bible

Then a revelation from the LORD came to Elijah:

Context

1Elijah ará Tiṣibi láti Tiṣbi ní Gileadi wí fún Ahabu pé, “Bí Olúwa Ọlọ́run Israẹli ti wà, ẹni tí èmi ń sìn, kì yóò sí ìrì tàbí òjò ní ọdún díẹ̀ tí ń bọ̀ bí kò ṣe nípa ọ̀rọ̀ mi.” 2Nígbà náà ni ọ̀rọ̀ Olúwa tọ Elijah wá pé, 3“Kúrò níhìn-ín, kọjú sí ìhà ìlà-oòrùn, kí o sì fi ara rẹ pamọ́ níbi odò Keriti, tí ń bẹ níwájú Jordani. 4Ìwọ yóò mu nínú odò náà, mo sì ti pàṣẹ fún àwọn ẹyẹ ìwò láti máa bọ́ ọ níbẹ̀.”

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.