1 Kronika 8:36
1 Chronicles 8:36 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ahasi jẹ́ baba a Jeheada, Jeheada jẹ́ baba a Alemeti, Asmafeti àti Simri, Simri sì jẹ́ baba Mosa.
1 Chronicles 8:36 in English
1 Chronicles 8:36 · Berean Standard Bible
Ahaz was the father of Jehoaddah, Jehoaddah * was the father of Alemeth, Azmaveth, and Zimri, and Zimri was the father of Moza.
Context
34Ọmọ Jonatani:
Meribu-Baali tí ó jẹ́ baba Mika. 35Àwọn ọmọ Mika:
Pitoni, Meleki, Tarea, àti Ahasi. 36Ahasi jẹ́ baba a Jeheada, Jeheada jẹ́ baba a Alemeti, Asmafeti àti Simri, Simri sì jẹ́ baba Mosa. 37Mosa jẹ́ baba Binea; Rafa sì jẹ́ ọmọ rẹ̀, Eleasa ọmọ rẹ̀ àti Aseli ọmọ rẹ̀. 38Aseli ní ọmọ mẹ́fà pẹ̀lú wọ̀nyí ni orúkọ wọn:
Asrikamu, Bokeru, Iṣmaeli, Ṣeariah, Obadiah àti Hanani. Gbogbo wọ̀nyí ni ọmọ Aseli.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.