1 Kronika 7:20
1 Chronicles 7:20 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ìran ọmọ Efraimu: Ṣutelahi, Beredi ọmọkùnrin rẹ̀, Tahati ọmọ rẹ̀, Eleadah ọmọ rẹ̀. Tahati ọmọ rẹ̀
1 Chronicles 7:20 in English
1 Chronicles 7:20 · Berean Standard Bible
The descendants of Ephraim: Shuthelah, Bered his son, Tahath his son, Eleadah his son, Tahath his son,
Context
18Arábìnrin rẹ̀. Hamoleketi bí Iṣhodi, Abieseri àti Mahila. 19Àwọn ọmọ Ṣemida sì jẹ́:
Ahiani, Ṣekemu, Likki àti Aniamu. 20Àwọn ìran ọmọ Efraimu:
Ṣutelahi, Beredi ọmọkùnrin rẹ̀,
Tahati ọmọ rẹ̀, Eleadah ọmọ rẹ̀.
Tahati ọmọ rẹ̀ 21Sabadi ọmọ, rẹ̀,
àti Ṣutelahi ọmọ rẹ̀.
Eseri àti Eleadi ni a pa nípasẹ̀ àwọn ọkùnrin bíbí ìbílẹ̀ Gati nígbà tí wọ́n sọ̀kalẹ̀ lọ láti lọ fi agbára mú ohun ọ̀sìn wọn 22Efraimu baba wọn ṣọ̀fọ̀ fún wọn ní ọjọ́ púpọ̀, àwọn ìbátan rẹ̀ wá láti tù ú nínú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.