1 Kronika 4:21
1 Chronicles 4:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ọmọ Ṣela ọmọ Juda: Eri baba Leka, Lada baba Meraṣa àti àwọn ìdílé ilé àwọn tí ń hun aṣọ oníṣẹ́ ní Beti-Aṣibea.
1 Chronicles 4:21 in English
1 Chronicles 4:21 · Berean Standard Bible
The sons of Shelah son of Judah: Er the father of Lecah, Laadah the father of Mareshah and the clans of the linen workers at Beth-ashbea,
Context
19Àwọn ọmọ aya Hodiah arábìnrin Nahamu,
baba Keila ará Garimu, àti Eṣitemoa àwọn ará Maakati. 20Àwọn ọmọ Ṣimoni:
Amnoni, Rina, Beni-Hanani àti Tiloni.
Àwọn ọmọ Iṣi:
Soheti àti Beni-Soheti. 21Àwọn ọmọ Ṣela ọmọ Juda:
Eri baba Leka, Lada baba Meraṣa àti àwọn ìdílé ilé àwọn tí ń hun aṣọ oníṣẹ́ ní Beti-Aṣibea. 22Jokimu, ọkùnrin Koseba, àti Joaṣi àti Sarafi, olórí ní Moabu àti Jaṣubi Lehemu. (Àkọsílẹ̀ yìí sì wà láti ìgbà àtijọ́.) 23Àwọn sì ni amọ̀kòkò tí ń gbé ní Netaimu àti Gedera; wọ́n sì dúró níbẹ̀ wọ́n sì ń ṣiṣẹ́ fún ọba.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.