1 Kronika 27:21
1 Chronicles 27:21 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
lórí ààbọ̀ ẹ̀yà Manase ní Gileadi: Iddo ọmọ Sekariah; lórí Benjamini: Jaasieli ọmọ Abneri;
1 Chronicles 27:21 in English
1 Chronicles 27:21 · Berean Standard Bible
over the half-tribe of Manasseh in Gilead was Iddo son of Zechariah; over Benjamin was Jaasiel son of Abner;
Context
19lórí Sebuluni: Iṣmaiah ọmọ Obadiah;
lórí Naftali: Jerimoti ọmọ Asrieli; 20lórí àwọn ará Efraimu: Hosea ọmọ Asasiah;
lórí ààbọ̀ ẹ̀yà Manase: Joẹli ọmọ Pedaiah; 21lórí ààbọ̀ ẹ̀yà Manase ní Gileadi: Iddo ọmọ Sekariah;
lórí Benjamini: Jaasieli ọmọ Abneri; 22lórí Dani: Asareeli ọmọ Jerohamu.
Wọ̀nyí ni àwọn ìjòyè lórí ẹ̀yà Israẹli. 23Dafidi kò kọ iye àwọn ọkùnrin náà ní ogún ọdún sẹ́yìn tàbí dín nítorí Olúwa ti ṣe ìlérí láti ṣe Israẹli gẹ́gẹ́ bí iye ìràwọ̀ ojú ọ̀run.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.