Native Bible

Psalms 69:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

nítorí ìtara ilé rẹ jẹ mí run, àti ẹ̀gàn àwọn tí ń gàn ọ́ ṣubú lù mí.

Psalms 69:9 in English

Psalms 69:9 · Berean Standard Bible

because zeal for Your house has consumed me,* and the insults of those who insult You have fallen on me.*

Context

7Nítorí rẹ ni mo ń ru ẹ̀gàn, ìtìjú sì bo ojú mi. 8Mo jẹ́ àjèjì si àwọn arákùnrin mi; àlejò sí àwọn arákùnrin ìyá mi; 9nítorí ìtara ilé rẹ jẹ mí run, àti ẹ̀gàn àwọn tí ń gàn ọ́ ṣubú lù mí. 10Nígbà tí mo sọkún tí mo sì ń fi àwẹ̀ jẹ ara mi ní ìyà èyí náà sì dín ẹ̀gàn mi kù; 11nígbà tí mo wọ aṣọ àkísà, àwọn ènìyàn ń pa òwe mọ́ mi.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.