Native Bible

Psalms 66:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ẹ kọrin ọlá orúkọ rẹ̀; ẹ kọrin ìyìnsí i.

Psalms 66:2 in English

Psalms 66:2 · Berean Standard Bible

Sing the glory of His name; make His praise glorious.

Context

1Ẹ hó ìhó ayọ̀ sí Ọlọ́run, ẹ̀yin ilẹ̀ gbogbo! 2Ẹ kọrin ọlá orúkọ rẹ̀; ẹ kọrin ìyìnsí i. 3Ẹ wí fún Ọlọ́run pé, “Ìwọ ti ní ẹ̀rù tó nínú iṣẹ́ rẹ! Nípa ọ̀pọ̀ agbára rẹ ni àwọn ọ̀tá rẹ yóò fi sìn ọ́. 4Gbogbo ayé ń wólẹ̀ fún ọ; wọn ń kọrin ìyìn sí ọ, wọ́n ń kọrin ìyìn sí orúkọ rẹ.” Sela.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.