Saamu 2:6
Psalms 2:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Èmi ti fi ọba mi sí ipò lórí Sioni, òkè mímọ́ mi.”
Psalms 2:6 in English
Psalms 2:6 · Berean Standard Bible
“I have installed My King on Zion, upon My holy mountain.”
Context
4Ẹni tí ó gúnwà lórí ìtẹ́ lọ́run rẹ́rìn-ín;
Olúwa fi wọ́n rẹ́rìn-ín ẹlẹ́yà. 5Nígbà náà ni yóò bá wọn wí ní ìbínú rẹ̀
yóò sì dẹ́rùbà wọ́n ní ìrunú rẹ̀, ó wí pé, 6“Èmi ti fi ọba mi sí ipò
lórí Sioni, òkè mímọ́ mi.” 7Èmi yóò sì kéde ìpinnu Olúwa:
Ó sọ fún mi pé, “Ìwọ ni ọmọ mi;
lónìí, èmi ti di baba rẹ. 8Béèrè lọ́wọ́ mi,
Èmi yóò jẹ́ kí orílẹ̀-èdè di ìní rẹ,
òpin ilé ayé yóò sì jẹ́ ogún rẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.