Saamu 136:17
Psalms 136:17 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Fún ẹni tí ó kọlu àwọn ọba ńlá; nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.
Psalms 136:17 in English
Psalms 136:17 · Berean Standard Bible
He struck down great kings His loving devotion endures forever.
Context
15Ṣùgbọ́n ó bi Farao àti ogun rẹ̀ ṣubú nínú Òkun pupa;
nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 16Fún ẹni tí ó sin àwọn ènìyàn rẹ̀ la aginjù já
nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 17Fún ẹni tí ó kọlu àwọn ọba ńlá;
nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 18Ó sì pa àwọn ọba olókìkí
nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé. 19Sihoni, ọba àwọn ará Amori
nítorí tí àánú rẹ̀ dúró láéláé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.