Saamu 132:12
Psalms 132:12 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Bí àwọn ọmọ rẹ̀ yóò bá pa májẹ̀mú mi mọ́ àti ẹ̀rí mi tí èmi yóò kọ́ wọn, àwọn ọmọ wọn pẹ̀lú yóò jókòó lórí ìtẹ́ rẹ láéláé.
Psalms 132:12 in English
Psalms 132:12 · Berean Standard Bible
If your sons keep My covenant and the testimony I will teach them, then their sons will also sit on your throne forever and ever.”
Context
10Nítorí tí Dafidi ìránṣẹ́ rẹ̀,
má ṣe yí ojú ẹni òróró rẹ padà. 11Olúwa ti búra nítòótọ́ fún Dafidi,
Òun kì yóò yípadà kúrò nínú rẹ̀,
nínú irú-ọmọ inú rẹ ni èmi ó gbé kalẹ̀ sí orí ìtẹ́ rẹ. 12Bí àwọn ọmọ rẹ̀ yóò bá pa májẹ̀mú mi mọ́
àti ẹ̀rí mi tí èmi yóò kọ́ wọn,
àwọn ọmọ wọn pẹ̀lú yóò jókòó lórí ìtẹ́ rẹ láéláé. 13Nítorí tí Olúwa ti yan Sioni:
ó ti fẹ́ ẹ fún ibùjókòó rẹ̀. 14Èyí ni ibi ìsinmi mi láéláé:
níhìn-ín ni èmi yóò máa gbé:
nítorí tí mo fẹ́ ẹ.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.