Native Bible

Psalms 117:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa, àti òtítọ́ Olúwa dúró láéláé. Ẹ yin Olúwa!

Psalms 117:2 in English

Psalms 117:2 · Berean Standard Bible

For great is His loving devotion toward us, and the faithfulness of the LORD endures forever. Hallelujah!*

Context

1Ẹ yin Olúwa, gbogbo ẹ̀yin orílẹ̀-èdè; ẹ pòkìkí rẹ̀, gbogbo ẹ̀yin ènìyàn. 2Nítorí ìfẹ́ ńlá rẹ̀ tí ó ní sí wa, àti òtítọ́ Olúwa dúró láéláé. Ẹ yin Olúwa!

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.