Native Bible

Psalms 114:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Nígbà tí Israẹli jáde ní Ejibiti, ilé Jakọbu láti inú ènìyàn àjèjì èdè

Psalms 114:1 in English

Psalms 114:1 · Berean Standard Bible

When Israel departed from Egypt, the house of Jacob from a people of foreign tongue,

Context

1Nígbà tí Israẹli jáde ní Ejibiti, ilé Jakọbu láti inú ènìyàn àjèjì èdè 2Juda wà ní ibi mímọ́, Israẹli wà ní ìjọba. 3Òkun sì rí i, ó sì wárìrì: Jordani sì padà sẹ́yìn.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.