Saamu 111:9
Psalms 111:9 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó rán ìràpadà sí àwọn ènìyàn rẹ̀: ó pàṣẹ májẹ̀mú rẹ̀ títí láé, mímọ́ àti ọ̀wọ̀ ni orúkọ rẹ̀.
Psalms 111:9 in English
Psalms 111:9 · Berean Standard Bible
He has sent redemption to His people; He has ordained His covenant forever; holy and awesome is His name.
Context
7Iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ jẹ́ òtítọ́ àti ìdájọ́;
gbogbo òfin rẹ̀ sì dájú. 8Wọ́n dúró láé àti láé,
ní òtítọ́ àti òdodo ni a ṣe wọ́n. 9Ó rán ìràpadà sí àwọn ènìyàn rẹ̀:
ó pàṣẹ májẹ̀mú rẹ̀ títí láé,
mímọ́ àti ọ̀wọ̀ ni orúkọ rẹ̀. 10Ìbẹ̀rù Olúwa ni ìpilẹ̀ṣẹ̀ ọgbọ́n:
òye dáradára ni yóò máa ṣe òfin rẹ̀,
ìyìn rẹ̀ dúró láé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.