Saamu 107:19
Psalms 107:19 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Nígbà náà wọ́n kígbe sí Olúwa nínú ìṣòro wọn, ó sì yọ wọ́n nínú ìdààmú wọn.
Psalms 107:19 in English
Psalms 107:19 · Berean Standard Bible
Then they cried out to the LORD in their trouble, and He saved them from their distress.
Context
17Ọ̀pọ̀ di aṣiwèrè nítorí ìrékọjá wọn
wọ́n sì pọ́n wọn lójú nítorí ẹ̀ṣẹ̀ wọn. 18Wọ́n kọ gbogbo oúnjẹ
wọ́n sì súnmọ́ ẹnu-ọ̀nà ikú. 19Nígbà náà wọ́n kígbe sí Olúwa nínú ìṣòro wọn,
ó sì yọ wọ́n nínú ìdààmú wọn. 20Ó rán ọ̀rọ̀ rẹ̀, ara wọn sì dá
ó sì yọ wọ́n nínú isà òkú. 21Ẹ jẹ́ kí wọ́n fi ọpẹ́ fún Olúwa nítorí ìṣeun ìfẹ́ rẹ̀ àti iṣẹ́ ìyanu rẹ̀ fún ọmọ ènìyàn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.