Saamu 106:2
Psalms 106:2 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ta ni ó lè ròyìn iṣẹ́ agbára Olúwa, ta ní lè sọ nípa ìyìn rẹ̀?
Psalms 106:2 in English
Psalms 106:2 · Berean Standard Bible
Who can describe the mighty acts of the LORD or fully proclaim His praise?
Context
1Yin Olúwa! Ẹ fi ìyìn fún
Olúwa, nítorí tí ó ṣeun.
Ẹ fi ọpẹ́ fún Olúwa nítorí tí ó ṣeun,
nítorí tí ìfẹ́ rẹ̀ dúró láéláé. 2Ta ni ó lè ròyìn iṣẹ́ agbára Olúwa,
ta ní lè sọ nípa ìyìn rẹ̀? 3Ìbùkún ni fún àwọn tí ń pa ìdájọ́ mọ́?
Ẹni tí n ṣe ohun tí ó tọ́. 4Rántí mi, Olúwa,
nígbà tí o bá fi ojúrere rẹ hàn,
wá sí ìhà mi nígbà tí ìwọ bá gbà wọ́n,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.