Native Bible

Proverbs 21:5 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ètè àwọn olóye jásí èrè bí ìkánjú ṣe máa ń fa òsì kíákíá.

Proverbs 21:5 in English

Proverbs 21:5 · Berean Standard Bible

The plans of the diligent bring plenty, as surely as haste leads to poverty.

Context

3Ṣíṣe ohun tí ó dára tí ó sì tọ̀nà ó ṣe ìtẹ́wọ́gbà sí Olúwa ju ẹbọ lọ. 4Ojú tí ó gbéga àti ọkàn ìgbéraga, ìmọ́lẹ̀ àwọn ènìyàn búburú, ẹ̀ṣẹ̀ ni! 5Ètè àwọn olóye jásí èrè bí ìkánjú ṣe máa ń fa òsì kíákíá. 6Ìṣúra tí a kójọ nípasẹ̀ ahọ́n tí ń parọ́ jẹ́ ìrì lásán àti ìkẹ́kùn ikú. 7Ìwà ipá àwọn ènìyàn búburú yóò wọ́ wọn lọ, nítorí wọ́n kọ̀ láti ṣe ohun tí ó tọ́.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.