Native Bible

Numbers 7:52 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀;

Numbers 7:52 in English

Numbers 7:52 · Berean Standard Bible

one male goat for a sin offering;

Context

50àwo wúrà kan tí ìwọ̀n rẹ̀ jẹ́ ṣékélì mẹ́wàá tí ó kún fún tùràrí; 51akọ ọ̀dọ́ màlúù kan, àgbò kan àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan fún ẹbọ sísun; 52akọ ewúrẹ́ kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀; 53màlúù méjì, àgbò márùn-ún, akọ ewúrẹ́ márùn-ún àti akọ ọ̀dọ́-àgùntàn ọlọ́dún kan márùn-ún, tí wọn ó fi rú ẹbọ àlàáfíà. Èyí ni ọrẹ Eliṣama ọmọ Ammihudu. 54Gamalieli ọmọ Pedasuri, olórí àwọn ọmọ Manase ni ó mú ọrẹ tirẹ̀ wá ní ọjọ́ kẹjọ.

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.