Nahumu 3:1
Nahum 3:1 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ègbé ni fún ìlú ẹ̀jẹ̀ nì, gbogbo rẹ̀ kún fún èké, ó kún fún olè, ìjẹ kò kúrò!
Nahum 3:1 in English
Nahum 3:1 · Berean Standard Bible
Woe to the city of blood, full of lies, full of plunder, never without prey.
Context
1Ègbé ni fún ìlú ẹ̀jẹ̀ nì,
gbogbo rẹ̀ kún fún èké,
ó kún fún olè,
ìjẹ kò kúrò! 2Ariwo pàṣán àti ariwo
kíkùn kẹ̀kẹ́ ogun
àti jíjó ẹṣin
àti gbígbọn kẹ̀kẹ́ ogun jìgìjìgì! 3Ológun orí ẹṣin ń fi ìgbónára
ju idà wọn mọ̀nàmọ́ná
ọ̀kọ̀ rẹ̀ ti ń dán yanran sí òkè!
Ọ̀pọ̀lọpọ̀ si ní àwọn ẹni tí a pa,
àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ òkú;
òkú kò sì ni òpin;
àwọn ènìyàn sì ń kọsẹ̀ lára àwọn òkú.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.