Joṣua 19:6
Joshua 19:6 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Beti-Lebaoti àti Ṣarueli, ìlú wọn jẹ́ mẹ́tàlá àti ìletò wọn.
Joshua 19:6 in English
Joshua 19:6 · Berean Standard Bible
Beth-lebaoth, and Sharuhen—thirteen cities, along with their villages.
Context
4Eltoladi, Betuli, Horma, 5Siklagi, Beti-Markaboti, Hasari Susa, 6Beti-Lebaoti àti Ṣarueli, ìlú wọn jẹ́ mẹ́tàlá àti ìletò wọn. 7Aini, Rimoni, Eteri àti Aṣani, ìlú wọn jẹ́ mẹ́rin àti ìletò wọn, 8àti gbogbo àwọn agbègbè ìlú wọ̀nyí títí dé Baalati-Beeri (Rama ní gúúsù).
Èyí ni ilẹ̀ ìní ẹ̀yà àwọn ọmọ Simeoni, agbo ilé, ní agbo ilé.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.