Joṣua 19:35
Joshua 19:35 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn ìlú olódi sì Siddimu, Seri, Hamati, Rakàti, Kinnereti,
Joshua 19:35 in English
Joshua 19:35 · Berean Standard Bible
The fortified cities were Ziddim, Zer, Hammath, Rakkath, Chinnereth,
Context
33ààlà wọn lọ láti Helefi àti igi ńlá ní Saananimu nímù; kọjá lọ sí Adami Nekebu àti Jabneeli dé Lakkumu, ó sì pín ní Jordani. 34Ààlà náà gba ìhà ìwọ̀-oòrùn lọ sí Asnoti-Tabori ó sì jáde ní Hukoki. Ó sì dé Sebuluni, ní ìhà gúúsù Aṣeri ní ìhà ìwọ̀-oòrùn àti Juda ní Jordani ní ìhà ìlà-oòrùn. 35Àwọn ìlú olódi sì Siddimu, Seri, Hamati, Rakàti, Kinnereti, 36Adama, Rama Hasori, 37Kedeṣi, Edrei, Eni-Aṣọri,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.