Jobu 33:18
Job 33:18 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Ó sì fa ọkàn rẹ̀ padà kúrò nínú isà òkú, àti ẹ̀mí rẹ̀ láti ṣègbé lọ́wọ́ idà.
Job 33:18 in English
Job 33:18 · Berean Standard Bible
to preserve his soul from the Pit and his life from perishing by the sword.
Context
16nígbà náà ni ó lè sọ̀rọ̀ ní etí wọn,
yóò sì dẹ́rùbà wọ́n pẹ̀lú ìbáwí, 17kí ó lè fa ènìyàn sẹ́yìn kúrò nínú ètè rẹ̀;
kí ó sì pa ìgbéraga mọ́ kúrò lọ́dọ̀ ènìyàn; 18Ó sì fa ọkàn rẹ̀ padà kúrò nínú isà òkú,
àti ẹ̀mí rẹ̀ láti ṣègbé lọ́wọ́ idà. 19“A sì nà án lórí ibùsùn ìrora rẹ̀;
pẹ̀lúpẹ̀lú a fi ìjà egungun rẹ̀ ti ó dúró pẹ́ nà án, 20bẹ́ẹ̀ ni ẹ̀mí rẹ kọ oúnjẹ,
ọkàn rẹ̀ sì kọ oúnjẹ dídùn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.