Jeremiah 31:1
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
“Nígbà náà, Èmi yóò jẹ́ Ọlọ́run fún gbogbo ìdílé ìran Israẹli, àwọn náà yóò sì jẹ́ ènìyàn mi,” ni Olúwa wí.
Jeremiah 31:1 in English
Jeremiah 31:1 · Berean Standard Bible
“At that time,” declares the LORD, “I will be the God of all the families of Israel, and they will be My people.”
Context
1“Nígbà náà, Èmi yóò jẹ́ Ọlọ́run fún gbogbo ìdílé ìran Israẹli, àwọn náà yóò sì jẹ́ ènìyàn mi,” ni Olúwa wí. 2Èyí ni ohun tí Olúwa wí:
“Àwọn ènìyàn tí ó sá àsálà lọ́wọ́ idà
yóò rí ojúrere Olúwa ní aṣálẹ̀,
Èmi yóò sì fi ìsinmi fún Israẹli.” 3Olúwa ti fi ara rẹ̀ hàn wá ní ìgbà kan rí, ó wí pé:
“Èmi ti nífẹ̀ẹ́ yín pẹ̀lú ìfẹ́ àìlópin;
mo ti fi ìfẹ́ ńlá fà yín,
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.