Isaiah 34:1
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Súnmọ́ tòsí, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè láti gbọ́, tẹ́tí sílẹ̀ ẹ̀yin ènìyàn jẹ́ kí ayé gbọ́, àti ẹ̀kún rẹ̀, ayé àti ohun gbogbo tí ó ti inú rẹ̀ jáde.
Isaiah 34:1 in English
Isaiah 34:1 · Berean Standard Bible
Come near, O nations, to listen; pay attention, O peoples. Let the earth hear, and all that fills it, the world and all that springs from it.
Context
1Súnmọ́ tòsí,
ẹ̀yin orílẹ̀-èdè láti gbọ́,
tẹ́tí sílẹ̀ ẹ̀yin ènìyàn
jẹ́ kí ayé gbọ́,
àti ẹ̀kún rẹ̀,
ayé àti ohun gbogbo tí ó ti inú rẹ̀ jáde. 2Nítorí ìbínú Olúwa ń bẹ
lára gbogbo orílẹ̀-èdè,
àti ìrunú rẹ̀ lórí gbogbo ogun wọn:
o ti fi wọ́n fún pípa. 3Àwọn ti a pa nínú wọn
ni a ó sì jù sóde,
òórùn wọn yóò ti inú òkú wọn jáde,
àwọn òkè ńlá yóò sì yọ̀ nínú ẹ̀jẹ̀ wọn.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.