Isaiah 2:22
Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Dẹ́kun à ń gba ènìyàn gbọ́, èémí ẹni tó wà ní ihò imú rẹ̀. Nítorí nínú kín ni a lè kà á sí?
Isaiah 2:22 in English
Isaiah 2:22 · Berean Standard Bible
Put no more trust in man, who has only the breath in his nostrils. Of what account is he?
Context
20Ní ọjọ́ náà ni àwọn ènìyàn yóò máa sọ
àwọn ère fàdákà àti ère wúrà
tí wọ́n ti yá fún bíbọ
sí èkúté àti àwọn àdán. 21Wọn yóò sálọ sínú ihò ìsàlẹ̀ àpáta
àti sínú ihò pàlàpálá àpáta
kúrò lọ́wọ́ ìpayà Olúwa
àti ògo ọláńlá rẹ̀,
nígbà tí ó bá dìde láti mi ayé tìtì. 22Dẹ́kun à ń gba ènìyàn gbọ́,
èémí ẹni tó wà ní ihò imú rẹ̀.
Nítorí nínú kín ni a lè kà á sí?
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.