Native Bible

Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017

Ègbé ni fún àwọn ti ń ṣe òfin àìṣòdodo,

Isaiah 10:1 in English

Isaiah 10:1 · Berean Standard Bible

Woe to those who enact unjust statutes and issue oppressive decrees,

Context

1Ègbé ni fún àwọn ti ń ṣe òfin àìṣòdodo, 2láti dún àwọn aláìní ní ẹ̀tọ́ wọn àti láti fa ọwọ́ ìdájọ́ sẹ́yìn kúrò níwájú àwọn olùpọ́njú ènìyàn mi, wọ́n sọ àwọn ọ̀pọ̀ di ìjẹ fún wọn, wọ́n sì ń ja àwọn aláìní baba lólè. 3Kí ni ìwọ yóò ṣe ní ọjọ́ ìṣirò nígbà tí ìparun bá ti ọ̀nà jíjìn wá? Ta ni ìwọ yóò sá tọ̀ fún ìrànlọ́wọ́? Níbo ni ìwọ yóò fi ọrọ̀ rẹ sí?

Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.