Gẹnẹsisi 36:15
Genesis 36:15 · Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible 2017
Àwọn wọ̀nyí ni olórí nínú àwọn ọmọ Esau: àwọn ọmọ Elifasi, àkọ́bí Esau, Temani, Omari, Sefi, Kenasi,
Genesis 36:15 in English
Genesis 36:15 · Berean Standard Bible
These are the chiefs among the sons of Esau. The sons of Eliphaz the firstborn of Esau: Chiefs Teman, Omar, Zepho, Kenaz,
Context
13Àwọn ọmọ Reueli:
Nahati, Sera, Ṣamma àti Missa. Àwọn ni ọmọ ọmọ Basemati aya Esau. 14Wọ̀nyí ni àwọn ọmọ Oholibama ọmọbìnrin Ana ọmọ ọmọ Sibeoni: tí ó bí fún Esau:
Jeuṣi, Jalamu àti Kora. 15Àwọn wọ̀nyí ni olórí nínú àwọn ọmọ Esau:
àwọn ọmọ Elifasi, àkọ́bí Esau,
Temani, Omari, Sefi, Kenasi, 16Kora, Gatamu àti Amaleki. Àwọn wọ̀nyí ló jẹ́ olórí ìdílé tí ó ti ọ̀dọ̀ Elifasi ní Edomu wá, wọ́n jẹ́ ọmọ ọmọ Adah. 17Wọ̀nyí sì ni àwọn ọmọ Esau, ọmọ Rueli:
Nahati olórí, Sera olórí, Ṣamma olórí, Missa olórí. Àwọn wọ̀nyí ló jẹ́ olórí ìdílé tí ó ti ọ̀dọ̀ Reueli jáde ní Edomu. Ọmọ ọmọ Basemati aya Esau ni wọ́n jẹ́.
Yorùbá text and audio: Biblica® Open Yorùbá Contemporary Bible™, made available under an open license by Biblica, Inc.